Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Daniẹli 9:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbọ́ tiwa, OLUWA, dáríjì wá, tẹ́tí sí wa, OLUWA, wá nǹkan ṣe sí ọ̀rọ̀ yìí, má sì jẹ́ kí ó pẹ́, nítorí orúkọ rẹ, tí a fi ń pe ìlú rẹ ati àwọn eniyan rẹ.”

Ka pipe ipin Daniẹli 9

Wo Daniẹli 9:19 ni o tọ