Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Daniẹli 6:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọba bá pàṣẹ pé kí wọ́n lọ mú Daniẹli, kí wọ́n sì jù ú sinu ihò kinniun. Ṣugbọn ó sọ fún Daniẹli pé, “Ọlọrun rẹ tí ò ń sìn láìsinmi yóo gbà ọ́.”

Ka pipe ipin Daniẹli 6

Wo Daniẹli 6:16 ni o tọ