Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Daniẹli 6:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọkunrin wọnyi gbìmọ̀, wọ́n sọ fún ọba pé, “Kabiyesi, o mọ̀ pé òfin Mede ati ti Pasia ni pé òfin tí ọba bá ṣe kò gbọdọ̀ yipada.”

Ka pipe ipin Daniẹli 6

Wo Daniẹli 6:15 ni o tọ