Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Kinni 8:59 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí OLUWA Ọlọrun wa ranti adura mi yìí ati gbogbo ẹ̀bẹ̀ tí mo bẹ̀ níwájú rẹ̀ yìí tọ̀sán-tòru, kí ó máa ti èmi iranṣẹ rẹ̀ lẹ́yìn nígbà gbogbo, ati àwọn ọmọ Israẹli, eniyan rẹ̀ pẹlu; máa tì wá lẹ́yìn bí ó bá ti tọ́ lojoojumọ,

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 8

Wo Àwọn Ọba Kinni 8:59 ni o tọ