Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Kinni 4:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Solomoni jọba lórí gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè, láti odò Yufurate títí dé ilẹ̀ Filistia, títí dé ààlà ilẹ̀ àwọn ará Ijipti. Wọ́n ń san ìṣákọ́lẹ̀ fún un, wọ́n sì ń sìn ín ní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 4

Wo Àwọn Ọba Kinni 4:21 ni o tọ