Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Kinni 21:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ahabu bá pada lọ sílé pẹlu ìrẹ̀wẹ̀sì ọkàn ati ibinu, nítorí ohun tí Naboti ará Jesireeli wí fún un. Ó dùbúlẹ̀ lórí ibùsùn rẹ̀, ó kọjú sí ògiri, kò sì jẹun.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 21

Wo Àwọn Ọba Kinni 21:4 ni o tọ