Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Kinni 21:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Naboti dáhùn pé, “Ọwọ́ àwọn baba ńlá mi ni mo ti jogún ọgbà àjàrà yìí; OLUWA má jẹ́ kí n rí ohun tí n óo fi gbé e fún ọ.”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 21

Wo Àwọn Ọba Kinni 21:3 ni o tọ