Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Kinni 16:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọdún kejidinlogoji tí Asa, ọba Juda gorí oyè ni Ahabu, ọmọ Omiri gorí oyè ní Israẹli, Ahabu sì jọba lórí Israẹli ní Samaria fún ọdún mejilelogun.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 16

Wo Àwọn Ọba Kinni 16:29 ni o tọ