Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Kinni 15:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Baaṣa gbógun ti ilẹ̀ Juda, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí mọ odi yí Rama po, kí ẹnikẹ́ni má baà rí ààyè lọ sí ọ̀dọ̀ Asa, ọba Juda, tabi kí ẹnikẹ́ni jáde kúrò lọ́dọ̀ rẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 15

Wo Àwọn Ọba Kinni 15:17 ni o tọ