Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Kinni 10:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ọbabinrin Ṣeba gbọ́ òkìkí ọgbọ́n Solomoni, ó wá sí Jerusalẹmu láti fi àwọn ìbéèrè tí ó takókó dán an wò.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 10

Wo Àwọn Ọba Kinni 10:1 ni o tọ