Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Kinni 1:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Adonija lọ jíròrò pẹlu Joabu, ọmọ Seruaya, ati Abiatari alufaa, àwọn mejeeji tẹ̀lé ọ̀rọ̀ rẹ̀, wọ́n sì ràn án lọ́wọ́.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 1

Wo Àwọn Ọba Kinni 1:7 ni o tọ