Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Kinni 1:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí wá ọdọmọbinrin tí ó lẹ́wà gidigidi ní gbogbo ilẹ̀ Israẹli. Wọ́n rí ọdọmọbinrin arẹwà kan ní ìlú Ṣunemu, tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Abiṣagi, wọ́n sì mú un tọ Dafidi wá.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 1

Wo Àwọn Ọba Kinni 1:3 ni o tọ