Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 7:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, wọ́n sọ fún ara wọn pé, “Ohun tí à ń ṣe yìí kò dára, ọjọ́ ìròyìn ayọ̀ ni ọjọ́ òní. Bí a bá dákẹ́, tí a sì dúró di òwúrọ̀ a óo jìyà. Ẹ jẹ́ kí á lọ sọ fún àwọn ará ilé ọba.”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 7

Wo Àwọn Ọba Keji 7:9 ni o tọ