Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 7:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àwọn adẹ́tẹ̀ mẹrin náà dé ìkangun ibùdó ogun, wọ́n wọ inú àgọ́ kan lọ. Wọ́n jẹ ohun tí wọ́n bá níbẹ̀; wọ́n sì mu. Wọ́n kó fadaka ati wúrà ati aṣọ tí wọ́n rí níbẹ̀, wọ́n lọ kó wọn pamọ́. Wọ́n pada wá, wọ́n wọ inú àgọ́ mìíràn, wọ́n tún ṣe bákan náà.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 7

Wo Àwọn Ọba Keji 7:8 ni o tọ