Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 7:19 BIBELI MIMỌ (BM)

ọ̀gágun náà dáhùn pé, “Ǹjẹ́ èyí lè ṣẹ, bí OLUWA tilẹ̀ rọ̀jò àwọn nǹkan wọnyi sílẹ̀ láti ojú ọ̀run wá.” Eliṣa sì dá a lóhùn pé, “O óo fi ojú rẹ rí i, ṣugbọn o kò ní jẹ ninu rẹ̀.”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 7

Wo Àwọn Ọba Keji 7:19 ni o tọ