Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 7:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí nígbà tí eniyan Ọlọrun sọ fún ọba pé, “Ní ìwòyí ọ̀la, lẹ́nu bodè Samaria, àwọn eniyan yóo máa ra òṣùnwọ̀n ìyẹ̀fun kíkúnná kan tabi òṣùnwọ̀n ọkà baali meji ní ìwọ̀n ṣekeli kọ̀ọ̀kan,”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 7

Wo Àwọn Ọba Keji 7:18 ni o tọ