Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 6:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ọ̀kan ninu wọn ti ń gé igi, lójijì, irin àáké tí ó ń lò yọ bọ́ sinu odò. Ó kígbe pé, “Yéè! Oluwa mi, a yá àáké yìí ni!”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 6

Wo Àwọn Ọba Keji 6:5 ni o tọ