Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 5:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bá sáré tẹ̀lé Naamani. Nígbà tí Naamani rí i pé ẹnìkan ń sáré bọ̀, ó sọ̀kalẹ̀ lórí kẹ̀kẹ́ ogun tí ó gùn láti pàdé rẹ̀, ó bèèrè pé, “Ṣé kò sí nǹkan?”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 5

Wo Àwọn Ọba Keji 5:21 ni o tọ