Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 25:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ni wọ́n lu odi ìlú náà, ọba ati àwọn ọmọ ogun rẹ̀ sì gba ibẹ̀ sá jáde lóru. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àwọn ará Kalidea yí ìlú náà po, wọ́n lu odi ìlú náà, wọ́n gba ẹnu ọ̀nà tí ó wà láàrin odi mejeeji lẹ́gbẹ̀ẹ́ ọgbà ọba, wọ́n sì gba ọ̀nà tí ó lọ sí Araba.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 25

Wo Àwọn Ọba Keji 25:4 ni o tọ