Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 22:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ṣe ohun tí ó dára lójú OLUWA, ó tẹ̀ sí ọ̀nà Dafidi, baba ńlá rẹ̀, kò sì ṣe nǹkankan tí ó lòdì sí àpẹẹrẹ tí Dafidi fi lélẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 22

Wo Àwọn Ọba Keji 22:2 ni o tọ