Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 22:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọmọ ọdún mẹjọ ni Josaya nígbà tí ó jọba, ó sì wà lórí oyè ní Jerusalẹmu fún ọdún mọkanlelọgbọn. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Jedida ọmọ Adaya ará Bosikati.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 22

Wo Àwọn Ọba Keji 22:1 ni o tọ