Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 2:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ wolii tí wọn ń gbé Bẹtẹli tọ Eliṣa wá, wọ́n bi í pé, “Ǹjẹ́ o mọ̀ pé OLUWA yóo mú ọ̀gá rẹ lọ lónìí?”Eliṣa dáhùn pé, “Bẹ́ẹ̀ ni, mo mọ̀, ṣugbọn ẹ má ṣe sọ ohunkohun nípa rẹ̀.”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 2

Wo Àwọn Ọba Keji 2:3 ni o tọ