Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 19:32 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ohun tí OLUWA sọ nípa ọba Asiria ni pé, kò ní wọ inú ìlú yìí, bẹ́ẹ̀ ni kò ní ta ọfà kankan sí i. Kò sí ọmọ ogun kan tí ó ní apata tí yóo wá sí ẹ̀bá ìlú náà, bẹ́ẹ̀ ni kò ní lè gbìyànjú láti gbógun tì í.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 19

Wo Àwọn Ọba Keji 19:32 ni o tọ