Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 19:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn eniyan yóo là ní Jerusalẹmu, àwọn eniyan yóo sì ṣẹ́kù ni Òkè Sioni, nítorí pé ìtara ni OLUWA yóo fi ṣe é.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 19

Wo Àwọn Ọba Keji 19:31 ni o tọ