Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 18:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọdún kẹrinla tí Hesekaya jọba ní Juda, ni Senakeribu, ọba Asiria, gbógun ti àwọn ìlú olódi Juda, ó sì ṣẹgun wọn.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 18

Wo Àwọn Ọba Keji 18:13 ni o tọ