Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 18:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ogun kó Samaria nítorí pé àwọn ọmọ Israẹli kò pa òfin OLUWA Ọlọrun wọn mọ́, wọ́n si da majẹmu tí OLUWA bá wọn dá. Wọn kò pa àwọn òfin tí OLUWA fún Mose, iranṣẹ rẹ̀ mọ́, wọn kò sì gbọ́ràn.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 18

Wo Àwọn Ọba Keji 18:12 ni o tọ