Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 18:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ní ọdún kẹta tí Hoṣea, ọmọ Ela, jọba ní Israẹli ni Hesekaya, ọmọ Ahasi jọba ní Juda.

2. Ẹni ọdún mẹẹdọgbọn ni nígbà tí ó jọba, ó sì jọba ní Jerusalẹmu fún ọdún mọkandinlọgbọn. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Abi, ọmọ Sakaraya.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 18