Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 18:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọdún kẹta tí Hoṣea, ọmọ Ela, jọba ní Israẹli ni Hesekaya, ọmọ Ahasi jọba ní Juda.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 18

Wo Àwọn Ọba Keji 18:1 ni o tọ