Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 17:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ogun kó Samaria nítorí pé àwọn ọmọ Israẹli ṣẹ̀ sí OLUWA Ọlọrun wọn ó gbà wọ́n lọ́wọ́ ọba Farao, tí ó sì kó wọn jáde kúrò ní Ijipti. Wọ́n ti bọ oriṣa,

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 17

Wo Àwọn Ọba Keji 17:7 ni o tọ