Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 17:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọdún kẹsan-an tí Hoṣea jọba, ọba Asiria ṣẹgun Samaria, ó sì kó àwọn ọmọ Israẹli ní ìgbèkùn lọ sí Asiria. Ó kó wọn sí ìlú Hala ati sí etí odò Habori tí ó wà ní agbègbè Gosani, ati sí àwọn ìlú Media.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 17

Wo Àwọn Ọba Keji 17:6 ni o tọ