Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 17:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n ń sin OLUWA, ṣugbọn wọ́n tún ń bọ àwọn oriṣa tí wọn ń bọ tẹ́lẹ̀ ní orílẹ̀-èdè tí olukuluku wọ́n ti wá.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 17

Wo Àwọn Ọba Keji 17:33 ni o tọ