Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 17:32 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn eniyan náà bẹ̀rù OLUWA pẹlu, wọ́n sì yan oniruuru eniyan lára wọn, láti máa ṣe alufaa níbi àwọn pẹpẹ oriṣa gíga, láti máa bá wọn rúbọ níbẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 17

Wo Àwọn Ọba Keji 17:32 ni o tọ