Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 17:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọba Asiria kó àwọn eniyan láti Babiloni, Kuta, Afa, Hamati ati Sefafaimu, ó kó wọn dà sinu àwọn ìlú Samaria dípò àwọn ọmọ Israẹli tí ó kó lọ. Wọ́n gba ilẹ̀ Samaria, wọ́n sì ń gbé inú àwọn ìlú rẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 17

Wo Àwọn Ọba Keji 17:24 ni o tọ