Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 17:23 BIBELI MIMỌ (BM)

títí tí OLUWA fi run wọ́n kúrò níwájú rẹ̀, bí ó ti kìlọ̀ fún wọn láti ẹnu àwọn wolii, iranṣẹ rẹ̀. Bẹ́ẹ̀ ni àwọn ará Asiria ṣe kó gbogbo àwọn ọmọ Israẹli lọ sí ìgbèkùn ní ilẹ̀ Asiria, níbi tí wọ́n wà títí di òní olónìí.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 17

Wo Àwọn Ọba Keji 17:23 ni o tọ