Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 15:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ṣe ohun burúkú níwájú OLUWA gẹ́gẹ́ bí àwọn baba rẹ̀ ti ṣe. Ó tẹ̀lé ìwà ẹ̀ṣẹ̀ Jeroboamu; ọmọ Nebati, tí ó mú Israẹli dẹ́ṣẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 15

Wo Àwọn Ọba Keji 15:9 ni o tọ