Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 15:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọdún kejidinlogoji tí Asaraya jọba ní Juda ni Sakaraya ọmọ Jeroboamu jọba lórí Israẹli, ní Samaria, ó sì wà lórí oyè fún oṣù mẹfa.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 15

Wo Àwọn Ọba Keji 15:8 ni o tọ