Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 15:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọdún kọkandinlogoji tí Asaraya ti jọba ní Juda ni Ṣalumu, ọmọ Jabeṣi, jọba lórí Israẹli, ní Samaria, ó wà lórí oyè fún oṣù kan.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 15

Wo Àwọn Ọba Keji 15:13 ni o tọ