Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 15:12 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ṣèlérí fún Jehu pé, “Àwọn ọmọ rẹ títí dé ìran kẹrin yóo jọba ní Israẹli.” Ó sì rí bẹ́ẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 15

Wo Àwọn Ọba Keji 15:12 ni o tọ