Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 14:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, Amasaya ranṣẹ sí Jehoaṣi, ọmọ Jehoahasi, ọmọ Jehu, ọba Israẹli, láti pè é níjà sí ogun.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 14

Wo Àwọn Ọba Keji 14:8 ni o tọ