Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 14:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Amasaya pa ẹgbaarun (10,000) ninu àwọn ọmọ ogun Edomu ní Àfonífojì Iyọ̀. Ó ṣẹgun Sela, ó sì yí orúkọ rẹ̀ pada sí Jokiteeli, orúkọ yìí ni ìlú náà ń jẹ́ títí di òní yìí.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 14

Wo Àwọn Ọba Keji 14:7 ni o tọ