Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 14:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọdún keji tí Jehoaṣi ọmọ Jehoahasi jọba ní Israẹli ni Amasaya ọmọ Joaṣi jọba ní Juda.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 14

Wo Àwọn Ọba Keji 14:1 ni o tọ