Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 11:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn olórí ogun náà gbọ́ àṣẹ tí Jehoiada, alufaa, pa fún wọn, wọ́n sì kó àwọn ọmọ ogun wọn, tí wọ́n ṣíwọ́ iṣẹ́ ní ọjọ́ ìsinmi ati àwọn tí wọn yóo wọ iṣẹ́ wá sí ọ̀dọ̀ rẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 11

Wo Àwọn Ọba Keji 11:9 ni o tọ