Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 11:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọn yóo dáàbò bo ọba pẹlu idà ní ọwọ́ wọn, wọn yóo sì máa bá a lọ sí ibikíbi tí ó bá ń lọ. Ẹnikẹ́ni tí ó bá súnmọ́ wọn, pípa ni kí wọ́n pa á.”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 11

Wo Àwọn Ọba Keji 11:8 ni o tọ