Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 10:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Jehu sì pàṣẹ fún ẹni tí ń tọ́jú ibi tí wọn ń kó aṣọ ìsìn pamọ́ sí pé kí ó kó wọn jáde fún àwọn tí ń bọ Baali.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 10

Wo Àwọn Ọba Keji 10:22 ni o tọ