Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 7:2 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA wí fún Gideoni pé, “Àwọn tí wọ́n wà pẹlu rẹ ti pọ̀jù fún mi, láti fi àwọn ará ilẹ̀ Midiani lé lọ́wọ́, kí àwọn ọmọ Israẹli má baà gbéraga pé agbára wọn ni wọ́n fi ṣẹgun, wọn kò sì ní fi ògo fún mi.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 7

Wo Àwọn Adájọ́ 7:2 ni o tọ