Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 7:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó yá, Gideoni, tí àdàpè rẹ̀ ń jẹ́ Jerubaali, ati àwọn eniyan tí wọ́n wà lọ́dọ̀ rẹ̀ gbéra ní òwúrọ̀ kutukutu ọjọ́ kan, wọ́n lọ pàgọ́ sí ẹ̀gbẹ́ odò Harodu. Àgọ́ ti àwọn ará Midiani wà ní apá ìhà àríwá wọn ní àfonífojì lẹ́bàá òkè More.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 7

Wo Àwọn Adájọ́ 7:1 ni o tọ