Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 6:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé, nígbà tí wọ́n bá ń bọ̀, tilé-tilé ni wọ́n wá. Wọn á kó àwọn àgọ́ wọn ati àwọn ẹran ọ̀sìn wọn lọ́wọ́, wọn á sì bo àwọn ọmọ Israẹli bí eṣú. Àwọn ati ràkúnmí wọn kò níye, nítorí náà nígbà tí wọ́n bá dé, wọn á jẹ gbogbo ilẹ̀ náà ní àjẹrun.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 6

Wo Àwọn Adájọ́ 6:5 ni o tọ