Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 6:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọn a gbógun tì wọ́n, wọn a sì ba gbogbo ohun ọ̀gbìn ilẹ̀ náà jẹ́ títí dé agbègbè Gasa. Wọn kì í fi oúnjẹ kankan sílẹ̀ rárá ní ilẹ̀ Israẹli, bẹ́ẹ̀ ni wọn kì í fi aguntan tabi mààlúù tabi kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ kankan sílẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 6

Wo Àwọn Adájọ́ 6:4 ni o tọ