Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 4:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Debora dáhùn pé, “Láìṣe àní àní, n óo bá ọ lọ. Ṣugbọn ṣá o, ohun tí o fẹ́ ṣe yìí kò ní já sí ògo fún ọ, nítorí pé, OLUWA yóo fi Sisera lé obinrin kan lọ́wọ́.” Debora bá gbéra, ó bá Baraki lọ sí Kedeṣi.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 4

Wo Àwọn Adájọ́ 4:9 ni o tọ