Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 4:15 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA mú ìdàrúdàpọ̀ bá Sisera ati gbogbo kẹ̀kẹ́ ogun rẹ̀ ati àwọn ọmọ ogun rẹ̀ níwájú Baraki. Bí àwọn ọmọ ogun Baraki ti ń fi idà pa wọ́n, Sisera sọ̀kalẹ̀ ninu kẹ̀kẹ́ ogun rẹ̀, ó bẹ̀rẹ̀ sí sá lọ.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 4

Wo Àwọn Adájọ́ 4:15 ni o tọ